Odura Oluwa

From Wikisource
Jump to navigation Jump to search

Odura Oluwa, the Lord's Prayer in Yoruba:

Baba wa ti mbẹ li ọrun
Ki a bọwọ fun orukọ rẹ
Ki Ijọba rẹ de
Ifẹ tire ni ki a ṣe
Bi ti orun, beni li aiye
Fun wa li onje Ojo wa loni
Dari gbese wa ji wa
Bi awa ti ndariji awon onigbese wa
Ma si fa wa sinu idewo
Sugbon gba wa lowo bilisi
Nitori ijo ba ni tire
Ati agbara, Ati ogo
Lailai, Amin